You are using an outdated browser. Please upgrade your browser to improve your experience.
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)

Eleyi jẹ Bibeli ni Yorùbá ni pipe pẹlu gbogbo awọn iwe ohun, orí ati awọn ẹsẹ

Eleyi jẹ Bibeli ni Yorùbá ni pipe pẹlu gbogbo awọn iwe ohun, orí ati awọn ẹsẹ

Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)

by Andrew Blurton
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)

What is it about?

Eleyi jẹ Bibeli ni Yorùbá ni pipe pẹlu gbogbo awọn iwe ohun, orí ati awọn ẹsẹ.. A ti fi ọpọlọpọ awọn ẹya ohun mere mere lati jẹki kika ati iwadi ti Bibeli re gbẹgẹ.

Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba)

App Details

Version
1.2
Rating
NA
Size
54Mb
Genre
Books Education
Last updated
September 13, 2017
Release date
May 6, 2015
More info

Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) is $2.99 but there are more add-ons

 • $0.99

  Awọn Ọba James Bible in English

 • $1.99

  Compare and Search Verses

 • $1.99

  Ilé ìkàwé

 • $3.99

  Gbogbo ìṣe

 • $0.99

  Apocrypha (English)

App Screenshots

Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) screenshot-0
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) screenshot-1
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) screenshot-2
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) screenshot-3
Bibeli Mimọ (The Bible in Yoruba) screenshot-4

App Store Description

Eleyi jẹ Bibeli ni Yorùbá ni pipe pẹlu gbogbo awọn iwe ohun, orí ati awọn ẹsẹ.. A ti fi ọpọlọpọ awọn ẹya ohun mere mere lati jẹki kika ati iwadi ti Bibeli re gbẹgẹ.


Wa’di
O le lo ohun elo iwa’di iṣẹ lati wa ẹsẹ Bibeli lori ero kan pato. Kọ rọra tẹ ọrọ ti ohun wa ki ‘app’ si gbe ẹsẹ ti o jẹmọ jade si ọ.


Fi awọn ẹsẹ han lori Facebook, Twitter ati Email


Ni bayi o le fi ẹsẹ lati nu Bibeli han awọn ọrẹ rẹ taara lori Facebook, Twitter tabi nipasẹ Email (ki o si fi erongba ọkan rẹ han).


Kọ Adura ati awon ero

Ọpọlọpọ awọn ti nlo ate eto wa n beere fun ohun ti wọn le lo lati le kọ awọn àdúrà wọn, ero tabi oro ti won gba nigbati wọn ba n ka Bibeli wọn. Ṣẹda adura arare ati ero re, fi wọn pamọ sinu awọn ‘app’ ati paapa fi wọn han si awọn ọrẹ rẹ lori Facebook, Twitter tabi nipasẹ email


Isaami si ẹsẹ


Nibayi o le saami ti o yatọ si awon ẹsẹ bibeli pelu awọn awọ ti o ba wu ọ. kọ rọra tẹ aworan geege nigba ti o ba n ka ọrọ Bibeli lọwọ

Bayi o le ri ese ti o yatọ ninu àwo ti o fẹ. Ko tẹ awọn aami ohun elo ikọwe bi o ba ka awọn ọrọ Bibeli

Bukumaaki


Bukumaaki yio ran ọ lọwọ lati sami si ibi tire ninu ọrọ bibeli. Awọn aami bukumaaki yi ni owa loke iboju. kọ fi ika tọ lati sami sori rẹ. Nigba ti o ba pada si ‘app’ tẹ aami ti owa loke ti iboju, yio si gbe ọ lọ sibi ti o ti kuro.


Wa ki o si se afiwe awọn ẹsẹ (Ni App)
Awọn ‘app’ yi ni o ni "iboju wẹẹrẹ" ti o jẹ ki o sese fun o lati wo ẹsẹ meji ni akoko kan na ati ki o le ka ki o si ṣe afiwe wọn l’ẹgbẹ ara won.


Ọpa Ìkẹkọọ - Išė Akojọ

Ṣẹda awọn iwe aṣẹ eleyọ tabi olọpọ ẹsẹ. Fi iwadi rẹ si ẹgbẹẹ àwọn ẹsẹ ọun. O le se ifiwe ran se (email) awọn iwe aṣẹ lati nu ‘app’.
Eda King James ni ede oyiboKa bibeli ti eda King James ni ede oyibo. Se afiwe awon ẹsẹ kankan lati nu eda ti Swedish pelu tie de oyibo.


Pe Wa


A n reti awọn esi rẹ. A ma n gbọ a si tun mu awọn ohun titun sinu ‘app’ na nipase awon arọwa yin. O le fi iwe ranṣẹ si wa nipasẹ awọn olubasọrọ wa ninu iṣẹ ‘app’ yi.

Disclaimer:
AppAdvice does not own this application and only provides images and links contained in the iTunes Search API, to help our users find the best apps to download. If you are the developer of this app and would like your information removed, please send a request to [email protected] and your information will be removed.